Njẹ Nitootọ Iwọ Di Atunbi Ni Ti Omi Ati Ẹmi Bi?

ebook

By Paul C. Jong

cover image of Njẹ Nitootọ Iwọ Di Atunbi Ni Ti Omi Ati Ẹmi Bi?

Sign up to save your library

With an OverDrive account, you can save your favorite libraries for at-a-glance information about availability. Find out more about OverDrive accounts.

   Not today

Find this title in Libby, the library reading app by OverDrive.

Download Libby on the App Store Download Libby on Google Play

Search for a digital library with this title

Title found at these libraries:

Library Name Distance
Loading...

Àkọ́lé ẹ̀kọ́ yìí gan an ni "lati di àtúnbí níti omi ati ti Ẹ̀mí." Ó ní ìpìlẹ̀ lórí ẹ̀kọ́ yìí. Ní èdè mìíràn, ìwé yìí fi nyé wa gedegbe ohun tí àtúnbí jẹ́ ati bí a ti lè di àtúnbí níti omi ati ti Ẹ̀mí ní ìbámu pẹlu Bibeli. Omi túmọ̀sí ìrìbọmi nínú odò Jọrdani Bibeli sì wipe gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ wa pátá ni ó ti rékọjá sórí Jesu nigbati Ó ṣe ìrìbọmi ní ọ̀dọ̀ Johannu Onítẹ̀bọmi. Johannu ni aṣojú gbogbo ẹ̀dá alààyè tí Ó sì tún jẹ̀ àrọ́mọdọ́mọ Aaroni Olórí alufa. Aaroni gbé ọwọ́ rẹ̀ méjèèjì lé orí ewúrẹ́ alààyè náà ó sì kó gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ Israẹli ti ọdọdún sórí rẹ̀ ní ọjọ́ ètùtù. Èyí jẹ́ òjìjí ohun rere tí mbọ̀ wá. Ìrìbọmi Jesu ni àpẹẹrẹ ètò ìgbọ́wọ́lé. Jesu ṣe ìrìbọmi ní ìlànà ètò ìgbọ́wọ́lé lórí nínú odò Jọrdani. Nitoridi èyí Ó kó gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ aiyé yìí lọ nípasẹ̀ ìrìbọmi Rẹ̀. Ó sì kú lórí àgbélèbú lati san gbèsè ẹ̀ṣẹ̀. Ṣugbọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ Kristiẹni ni kò mọ ìdí tí
Jesu fi ṣe ìrìbọmi ní ọ̀dọ̀ Johannu Onítẹ̀bọmi nínú odò Jọrdani. Ìrìbọmi Jesu ni kókó ọ̀rọ̀ ìwé yìí, ati apákan tí ó jẹ́ dandan sí ìhìnrere ti omi ati ti Ẹ̀mí. A lè di àtúnbí bí a bá nígbàgbọ́ sí ìrìbọmi ti Jesu ati ti ikú Rẹ̀ lórí igi àgbélèbú.

Njẹ Nitootọ Iwọ Di Atunbi Ni Ti Omi Ati Ẹmi Bi?